Oré - Aṣa

Oré - Aṣa

  • Альбом: Beautiful Imperfection

  • 출시년도: 2011
  • 언어: 순다어
  • 지속: 4:39

아래는 노래 가사입니다. Oré , 아티스트 - Aṣa 번역 포함

노래 가사 " Oré "

번역이 포함된 원본 텍스트

Oré

Aṣa

Ma ya lé mi iwo orè atojubo onilé

Ma ya lé mi iwo orè agbok’oloko

Ma ya lé mi awon orè adugbo

Ma ya lé mi ma ya lé k’omo

Orè ti mo mu bi aburo

Orè, orè ti mo sé daara dara

Orè ti mo fi nu hun

Owa daami o tumi sita

Odabi oro ano

Bi oro ano

Don’t come to my house

Iwo orè éké adugbo

Don’t come to my house

Iwo orè adaléru

Maya lé mi, orè kofeniferé

Maya lé mio maya lé rara

Isè ni mo wa lojo yi o

Oko t’o fèmi si lè

Ko ku lo wa sè sé

La won mejéji, won bèrè isé kusé

Won wuma omodé, won sé wun won

Odabi oro ano

Bi oro ano

Ewa wo ija lo jo yen

Ewa wo éro ton tu ta

Ewa wo ara lojo yen

Ejé rée ni le

Ma ya le mi toro iyo

Ma ya le mi toro ata

Ma ya mi le rara

Isé ku sé kun owo rè

I don’t want to see you no more

200만 개 이상의 가사

다양한 언어로 된 노래

번역

모든 언어로 고품질 번역

빠른 검색

몇 초 만에 원하는 텍스트를 찾으세요